Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Numeri 4:40 - Bibeli Mimọ

40 Ani awọn ti a kà ninu wọn, nipa idile wọn, gẹgẹ bi ile baba wọn, jẹ́ ẹgbẹtala o le ọgbọ̀n.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

40 jẹ́ ẹgbẹtala ó lé ọgbọ̀n (2,630).

Sien die hoofstuk Kopieer

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

40 Iye wọn nípa ìdílé àti ilé baba wọn jẹ́ ẹgbẹ̀tàlá ó-lé-ọgbọ̀n (2,630).

Sien die hoofstuk Kopieer




Numeri 4:40

Volg ons:

Advertensies


Advertensies