Numeri 3:29 - Bibeli Mimọ29 Awọn idile ti awọn ọmọ Kohati ni ki o pagọ́ lẹba agọ́ si ìha gusù. Sien die hoofstukYoruba Bible29 Àwọn ọmọ Kohati yóo pàgọ́ tiwọn sí ẹ̀gbẹ́ Àgọ́ Àjọ ní ìhà gúsù. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Àwọn ìdílé Kohati yóò pa ibùdó wọn sí ìhà gúúsù ní ẹ̀gbẹ́ àgọ́. Sien die hoofstuk |