Numeri 3:24 - Bibeli Mimọ24 Ati Eliasafu ọmọ Laeli ni ki o ṣe olori ile baba awọn ọmọ Gerṣoni. Sien die hoofstukYoruba Bible24 Eliasafu ọmọ Laeli ni yóo jẹ́ olórí wọn. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní24 Olórí àwọn ìdílé Gerṣoni ni Eliasafu ọmọ Láélì. Sien die hoofstuk |