Numeri 1:47 - Bibeli Mimọ47 Ṣugbọn awọn ọmọ Lefi gẹgẹ bi ẹ̀ya baba wọn li a kò kà mọ́ wọn. Sien die hoofstukYoruba Bible47 Ṣugbọn wọn kò ka àwọn ọmọ Lefi mọ́ wọn, Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní47 A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù. Sien die hoofstuk |