Marku 7:23 - Bibeli Mimọ23 Lati inu wá ni gbogbo nkan buburu wọnyi ti ijade, nwọn a si sọ enia di alaimọ́. Sien die hoofstukYoruba Bible23 Láti inú ni gbogbo àwọn nǹkan ibi wọnyi ti ń wá, àwọn ni ó ń sọ eniyan di aláìmọ́.” Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní23 Gbogbo àwọn nǹkan búburú wọ̀nyí ń tí inú wá, àwọn ló sì ń sọ yín di aláìmọ́.” Sien die hoofstuk |