Marku 7:21 - Bibeli Mimọ21 Nitori lati inu, lati inu ọkàn enia ni iro buburu ti ijade wá, panṣaga, àgbere, ipania, Sien die hoofstukYoruba Bible21 Nítorí láti inú ọkàn eniyan ni ète burúkú ti ń jáde: ìṣekúṣe, olè jíjà, ìpànìyàn, Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Nítorí pé láti inú ọkàn ènìyàn ni àwọn èrò búburú wọ̀nyí ti ń jáde wá: àgbèrè, olè, ìpànìyàn, panṣágà, Sien die hoofstuk |