Marku 7:20 - Bibeli Mimọ20 O si wipe, Eyi ti o ti inu enia jade, eyini ni isọ enia di alaimọ́. Sien die hoofstukYoruba Bible20 Ó tún fi kún un pé, “Àwọn nǹkan tí ń jáde láti inú eniyan ni ó ń sọ ọ́ di aláìmọ́. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní20 Nígbà náà, ó fi kún un pé: “Èyí ti ó ti ọkàn ènìyàn jáde ni ń sọ ni di aláìmọ́. Sien die hoofstuk |