Marku 6:49 - Bibeli Mimọ49 Ṣugbọn nigbati nwọn ri ti o nrìn loju omi, nwọn ṣebi iwin ni, nwọn si kigbe soke: Sien die hoofstukYoruba Bible49 Nígbà tí wọn rí i tí ó ń rìn lórí omi, wọ́n ṣebí iwin ni, wọ́n bá kígbe. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní49 ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n rí i tí ó ń rìn, wọ́n rò pé iwin ni. Wọ́n sì kígbe sókè lóhùn rara, Sien die hoofstuk |