Marku 6:32 - Bibeli Mimọ32 Nwọn si ba ti ọkọ̀ lọ si ibi ijù awọn nikan. Sien die hoofstukYoruba Bible32 Wọ́n bá bọ́ sinu ọkọ̀ ojú omi kan, wọ́n fẹ́ yọ́ lọ sí ibi tí kò sí eniyan. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní32 Nítorí náà, wọ́n wọ ọkọ̀ ojú omi kúrò níbẹ̀ lọ sí ibi tí ó parọ́rọ́. Sien die hoofstuk |