Marku 4:18 - Bibeli Mimọ18 Awọn wọnyi li awọn ti a fun sarin ẹgún; awọn ti o gbọ́ ọ̀rọ na, Sien die hoofstukYoruba Bible18 Àwọn mìíràn dàbí irúgbìn tí a fún sórí ilẹ̀ ẹlẹ́gùn-ún, wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní18 Àwọn tí ó bọ́ sáàrín ẹ̀gún ni àwọn tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, tí wọn sì gbà á. Sien die hoofstuk |