Marku 3:25 - Bibeli Mimọ25 Bi ile kan ba si yàpa si ara rẹ̀, ile na kì yio le duro. Sien die hoofstukYoruba Bible25 Bí àwọn ará ilé kan náà bá ń bá ara wọn jà, ilé náà kò lè fi ìdí múlẹ̀. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní25 Bákan náà, bí ilé kan bá sì yapa sí ara rẹ, ilé náà kí yóò le è dúró. Sien die hoofstuk |