Joẹli 1:15 - Bibeli Mimọ15 A! fun ọjọ na, nitori ọjọ Oluwa kù si dẹ̀dẹ, ati bi iparun lati ọwọ́ Olodumare ni yio de. Sien die hoofstukYoruba Bible15 Ó ṣe! Ọjọ́ náà ń bọ̀, ọjọ́ OLUWA dé tán! Ọjọ́ náà yóo dé bí ọjọ́ ìparun láti ọ̀dọ̀ Olodumare. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní15 A! Fún ọjọ́ náà, nítorí ọjọ́ Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀, yóò de bí ìparun láti ọwọ́ Olódùmarè. Sien die hoofstuk |