Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Esteri 9:29 - Bibeli Mimọ

29 Nigbana ni Esteri ayaba, ọmọbinrin Abihaili, ati Mordekai, ara Juda, fi ọlá gbogbo kọwe, lati fi idi iwe keji ti Purimu yi mulẹ.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

29 Ẹsita Ayaba, ọmọbinrin Abihaili, ati Modekai, tíí ṣe Juu kọ ìwé láti fi ìdí ìwé keji nípa Purimu múlẹ̀.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

29 Bẹ́ẹ̀ ni Esteri ayaba, ọmọbìnrin Abihaili, pẹ̀lú Mordekai ará a Júù, kọ̀wé pẹ̀lú àṣẹ láti fi ìdí ìwé kejì nípa Purimu yìí múlẹ̀.

Sien die hoofstuk Kopieer




Esteri 9:29

Volg ons:

Advertensies


Advertensies