Esteri 9:11 - Bibeli Mimọ11 Li ọjọ na a mu iye awọn ti a pa ni Ṣuṣani ãfin wá siwaju ọba. Sien die hoofstukYoruba Bible11 Ní ọjọ́ náà, wọ́n mú ìròyìn iye àwọn tí wọ́n pa ní Susa wá fún ọba. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní11 Ní ọjọ́ náà gan an ni a mú iye àwọn tí a pa ní ilé ìṣọ́ ti Susa wá fún ọba. Sien die hoofstuk |