Esteri 5:11 - Bibeli Mimọ11 Hamani si ròhin ogo ọrọ̀ rẹ̀, ati ọ̀pọlọpọ awọn ọmọ rẹ̀, ati ninu ohun gbogbo ti ọba fi gbe e ga, ati bi o ti gbe on ga jù awọn ijoye, ati awọn ọmọ-ọdọ ọba lọ. Sien die hoofstukYoruba Bible11 ó bẹ̀rẹ̀ sí fọ́nnu fún wọn bí ọrọ̀ rẹ̀ ti pọ̀ tó, iye àwọn ọmọ rẹ̀, bí ọba ṣe gbé e ga ju gbogbo àwọn ìjòyè ati àwọn olórí yòókù lọ. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní11 Hamani gbéraga sí wọn nípa títóbi ọ̀rọ̀ rẹ̀, púpọ̀ àwọn ọmọ rẹ̀, àti gbogbo ọ̀nà tí ọba ti bu ọlá fún un àti bí ó ṣe gbé e ga ju àwọn ọlọ́lá àti àwọn ìjòyè tókù lọ. Sien die hoofstuk |