Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Esteri 10:1 - Bibeli Mimọ

1 AHASWERUSI ọba si fi owo ọba le ilẹ fun gbogbo ilẹ, ati gbogbo erekùṣu okun.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

1 Ọba Ahasu-erusi pàṣẹ pé kí àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n jìnnà ati àwọn tí wọn ń gbé etíkun máa san owó orí.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

1 Ọba Ahaswerusi sì fi owó ọba lélẹ̀ jákèjádò ilẹ̀ ọba, dé erékùṣù Òkun

Sien die hoofstuk Kopieer




Esteri 10:1

Volg ons:

Advertensies


Advertensies