Esteri 1:9 - Bibeli Mimọ9 Faṣti ayaba sè àse pẹlu fun gbogbo awọn obinrin ni ile ọba ti iṣe ti Ahaswerusi. Sien die hoofstukYoruba Bible9 Ayaba Faṣiti pàápàá se àsè fún àwọn obinrin ní ààfin ọba Ahasu-erusi. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Ayaba Faṣti náà ṣe àsè fún àwọn obìnrin ní ààfin ọba Ahaswerusi. Sien die hoofstuk |