Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Eksodu 6:8 - Bibeli Mimọ

8 Emi o si mú nyin lọ sinu ilẹ na, ti mo ti bura lati fi fun Abrahamu, fun Isaaki, ati fun Jakobu; emi o si fi i fun nyin ni iní: Emi li OLUWA.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

8 N óo sì ko yín wá sí ilẹ̀ tí mo búra láti fún Abrahamu, ati Isaaki ati Jakọbu; n óo fún yín gẹ́gẹ́ bí ìní, Èmi ni OLUWA.’ ”

Sien die hoofstuk Kopieer

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

8 Èmi yóò mú un yín wá ilẹ̀ náà ti èmi ti búra pẹ̀lú ìgbọ́wọ́sókè láti fi fún Abrahamu. Isaaki àti Jakọbu. Èmi yóò fi fún un yín bí ohun ìní, Èmi ni Olúwa.’ ”

Sien die hoofstuk Kopieer




Eksodu 6:8

Volg ons:

Advertensies


Advertensies