Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Eksodu 4:22 - Bibeli Mimọ

22 Iwọ o si wi fun Farao pe, Bayi li OLUWA wi, Ọmọ mi ni Israeli, akọ́bi mi:

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

22 O óo wí fún un pé, Èmi, OLUWA wí pé, ‘Israẹli ni àkọ́bí mi ọkunrin.

Sien die hoofstuk Kopieer

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

22 Lẹ́yìn náà, kí o sọ fún Farao pé, ‘Èyí ni Olúwa sọ: Israẹli ní àkọ́bí ọmọ mi ọkùnrin,

Sien die hoofstuk Kopieer




Eksodu 4:22

Volg ons:

Advertensies


Advertensies