Eksodu 4:13 - Bibeli Mimọ13 On si wipe, Oluwa, emi bẹ̀ ọ, rán ẹniti iwọ o rán. Sien die hoofstukYoruba Bible13 Ṣugbọn Mose tún ní, “OLUWA mi, mo bẹ̀ ọ́, rán ẹlòmíràn.” Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 Mose dáhùn ó wí pé, “Olúwa jọ̀wọ́ rán ẹlòmíràn láti lọ ṣe iṣẹ́ yìí.” Sien die hoofstuk |