Aanlyn Bybel

- Advertensies -




Eksodu 4:12 - Bibeli Mimọ

12 Njẹ lọ nisisiyi, emi o si pẹlu ẹnu rẹ, emi o si kọ́ ọ li eyiti iwọ o wi.

Sien die hoofstuk Kopieer

Yoruba Bible

12 Nítorí náà, lọ, n óo sì wà pẹlu rẹ, n óo sì máa kọ́ ọ ní ohun tí o óo sọ.”

Sien die hoofstuk Kopieer

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

12 Lọ nísinsin yìí, èmi yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti sọ̀rọ̀. Èmi yóò sì kọ́ ọ ni ohun ti ìwọ yóò sọ.”

Sien die hoofstuk Kopieer




Eksodu 4:12

Volg ons:

Advertensies


Advertensies