Daniẹli 1:6 - Bibeli Mimọ6 Njẹ ninu awọn wọnyi ni Danieli, Hananiah, Miṣaeli, ati Asariah, lati inu awọn ọmọ Juda: Sien die hoofstukYoruba Bible6 Daniẹli, ati Hananaya, ati Miṣaeli ati Asaraya wà lára àwọn tí wọ́n ṣà ninu ẹ̀yà Juda. Sien die hoofstukBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Lára àwọn wọ̀nyí ni àwọn tó wá láti Juda: Daniẹli, Hananiah, Miṣaeli àti Asariah. Sien die hoofstuk |